A bá àwọn ọmọ Nàìjíríà sọ̀rọ̀ nípa àyájọ́ ijọ̀ba àwarawa lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, June 12, àti bí ìjọba Ààrẹ Bọlá Tinubu ṣe ń mú un ní ọ̀kúnkúndùn tó. Ọ̀pọ̀ èèyàn ló fi ẹ̀dùn ọkàn wọn hàn nípa bí ìjọba àwarawa lásìkò Ààrẹ Tinubu nígbà tí àwọn mìíràn ní ìrètí pé ohun gbogbo yóò tó máa lọ
Check Also
PHOTOS: Adamawa police arrest two for store breaking, theft
The Adamawa State Police Command has arrested two suspects in connection with a store breaking …