A ṣe àbẹ̀wò sí arábìnrin Adérónkẹ́ Adéṣọlá Olorì Sports ní ilé iṣẹ́ Splash FM ìlú Ìbàdàn láti sọ nípa iṣẹ́ pàtàkì tí ó ń ṣe nípa ṣíṣe àtúpalẹ̀ eré ìdárayá pẹ̀lú ẹ̀fẹ̀ lórí rédíò lédè Yorùbá. Olorì Sports ṣàlàyé bí ó ṣe di ògbóǹtarìgì sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ lédè Yorùbá, àwọn tí wọ́n ràn án lọ́wọ́ láti gòkè
Check Also
Police detain two for stealing 85 goats,sheep in Gombe
The Police Command in Gombe State has apprehended two suspects for allegedly stealing 57 goats …